Testo Alpha & Omega - Zlatan

Alpha & Omega - Zlatan
Informazioni sulla canzone In questa pagina puoi leggere il testo della canzone Alpha & Omega , di -Zlatan
Canzone dall'album: Symbol of Hope
Nel genere:Африканская музыка
Data di rilascio:16.10.2025
Etichetta discografica:Zanku

Seleziona la lingua in cui tradurre:

Alpha & Omega
Hustle everyday and night
Pray make them no stain my white
Even when I go all the way (Still many people go backbite)
The future bright
Every likkle thing would be alright
You can never know who is who (Pray make Oluwa dey my side)
Mo pe Alpha ati Omega
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko maa lọ bee
Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ
Iya ati Baba Lọla lo bi mi ṣugbọn mo tunra mi bi
Ẹlẹdaa mi fẹ sun mo dabara bo o ko ji
Darukọ iṣẹ jamajama kan ti mi o ṣe ri
Mo gbe pọnnpọ pa sẹ diẹ lo ku sẹ ki igun mi pa lori
Baba pastor o tete mọ pe Zanku n fo window lo si show, dagboru pẹlu kito
Femi Brookeey lo kọkọ mu mi lọ si studio
Orin were mo kọ ju, awọn temi lo dun bi kopiko
Mi o le gbagbe awọn nigga mi, awọn l'ọn ginger mi
Ti n ba wa owo studio ti wọn a towo bapo knicker mi
Ten toes on my grind nisin mo dọmọ to sabi
Up Agbede ni Ikorodu awọn temi l'Onigari
That time!
Oh my Lordy wọn ni ko le lọ far
Wọn ni bawo lẹni ti o niṣẹ ṣe ma san tithes (Awọn bastard)
Bi orukọ ọmọ mi Toluwalaṣẹ
Unstoppable bo wun wọn k'ọn gbajẹ
Mo pe Alpha ati Omega
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko maa lọ bee
Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ
Mo pada dọmọ t'ọn fi n yangan
Ọmọ t'ọn fi n tọrọ, irọ o da ma mẹnu le ọmọ jọmọ lọ
Pain in the ass ti o common fun awọn doubting Thomas
Eewo ti mu wọn lẹnu aje wọn le sọrọ mọ
I go dey always remember
When I wan cook but gas no dey cylinder
I was born to do wonders
But ogun idile no wan gimme chance
Never you say never!
My life story na big ginger
'Symbol of Hope', e dey play, e dey choke
Steady motivation fawọn temi ninu hole
Mo pe Alpha ati Omega
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko maa lọ bee
Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ
Ko yẹ ko maa lọ bee
Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ

Scrivi cosa pensi del testo!

Altre canzoni dell'artista:

NomeAnno
2019
2024
Jeserawa
ft. Idowest
2025
2025
2019
2019
2025
2019
2019
2019
2019
2019
Super Power
ft. Davido, Yonda
2019
2019
2019
If You No Know
ft. Jamo Pyper, PapiSnoop
2019
2019
2019
2019
2019